Unit 5 – Dialogue 1 “Nnkan ojà àti aso” (Market products and clothing)

Kimberly now tells Tunji remaining things she needs for her house. KIMBERLY: Sé o máà lè lo sójà pèlú mi lóla? TUNJI: O ò tí ì so nnkan tí o so pé o fé lo rà l’ójà fún mi. KIMBERLY: Mo fé ra èro telifísònnù TUNJI: Kí l’o fé fi  èro telifísònnù se pèlú gbogbo isé re … More Unit 5 – Dialogue 1 “Nnkan ojà àti aso” (Market products and clothing)

Reading Comprehension – Unit 4

Read the following passage and then answer the questions that follow: Arábinrin Adeolá Òsó ní ilé kan ní ìlú Èkó. Ilé yìí ní yàrá mérin, ibalùwè méta, ilé ìdáná kan, pálò méjì, àti ilé-ìjeun kan. Bóngálò kan wà léhìn ilé yìí. Fúláàtì kan tún wà láàárín ilé yìí àti bóngálò. Aránbinrin Òsó àti ebí rè … More Reading Comprehension – Unit 4

Vocabulary – Unit 4

Adigunjalè Armed robbers àti béè béè lo etc. àtiwo entrance àwo plates béèdì bed Bí béè kó If not so bí i like Bóngálò Bungalow Dára Good/nice Dárúko To name Dín to be less e object pronoun “you” (sing.) Eélòó ni? How much is it? Egbèrún a thousand Elòmíràn another person E seun Thank you … More Vocabulary – Unit 4

Visiting Nigeria – Kajaru Castle in Kaduna

Contrary to speculations, the Kajuru Castle located in Kaduna is not an ancient monument. Interestingly, it was built in 1978 by a controversial German expatriate who lived in Kaduna at the time. This breathtaking architectural master-piece is a tourist wonder of sorts. The style is very European and clearly German with a baronial hall, complete … More Visiting Nigeria – Kajaru Castle in Kaduna