Unit 1 – Dialogue 2

Two hours later, around 9:00 pm, Kunle goes back to look for Tunji. He sees Tunji’s younger brother, Sanya. KÚNLÉ: Báwo ni Sànyà? SÀNYÀ: Dáadáa ni. E káalé. KÚNLÉ: Òo, káalé. Ègbón e dà? SÀNYÀ: Won kò tí ì dé. KÚNLÉ: Kò burú, màá padà wá lóla SÀNYÀ: Kò burú. E sé, ó dàárò. KÚNLÉ: O sé, ó … More Unit 1 – Dialogue 2

Dialogue 1: N’ílé òré (at a friend’s house)

Kunle stops by Tunji’s house to say hello to him, but Tunji is not at home. Tunji’s mother speaks with Kunle. KÚNLÉ: E kúùròlé Mà MÀMÁ TÚNJÍ: Òo, kúùròlé. Báwo ni nnkan? KÚNLÉ: Dáadáa ni. E jòó mà, Túnjí nkó? Se ó wà n’lé? MÀMÁ TÚNJÍ: Rárá, kò sí n’lé. Ó lo sódò òré è Délé. KÚNLÉ: Kò … More Dialogue 1: N’ílé òré (at a friend’s house)