2nd Dialogue – Unit 2

Dupe Makinde meets her former teacher Mrs. Odunsi on her way home from school. DÚPÉ: E káàsán Mà ARÁBÌNRIN ODÚNSÌ: Òo, káàsán. Báwo ni nnkan? DÚPÉ: Dáadáa ni. ARÁBÌNRIN ODÚNSÌ: Ó péjó méta. DÚPÉ: Ojó kan pèlú Mà. ARÁBÌNRIN ODÚNSÌ: S’álàáfíà ni? DÚPÉ: A dúpé Mà. ARÁBÌNRIN ODÚNSÌ: Ilé nkó? DÚPÉ: Ó wà. ARÁBÌNRIN ODÚNSÌ: Isé nkó? DÚPÉ: Ó n lo dáadáa. ARÁBÌNRIN … More 2nd Dialogue – Unit 2

Dialogue unit 2 -Ìkíni àti ìpàdé (Greetings and meetings)

Dupe Makinde wakes up in the morning and greets her father, Mr. Makinde, before he leaves home for his office. DÚPÉ: (kneeling down) E káàárò, Sà. BÀBÁ DÚPÉ: Káàárò, pèlé. Sé dáadáa l’o jí? DÚPÉ: A dúpé Sà. BÀBÁ DÚPÉ: Sé o ti jeun? DÚPÉ: Rárá Sà. Mo sèsè jí ni. BÀBÁ DÚPÉ: Tètè lo jeun. Èmi n lo síbi … More Dialogue unit 2 -Ìkíni àti ìpàdé (Greetings and meetings)