Dialogue 1 – Unit 3 “Sísòrò nípa ènìyàn” (Talking about people)

Kunle came back the next day and found Tunji. KÚNLÉ: Túnjí, báwo ni nnkan? TÚNJÍ: Dáadáa ni. Jòwó má bínú. KÚNLÉ: Níbo l’o lo lálé àná? Mo wá sí ilé e léèmejì lálé àná. TÚNJÍ: Mo gbó béè. Mo lo rí omo kíláàsì mi kan ni. KÚNLÉ: Kí l’orúko è? TÚNJÍ: Kimberly. KÚNLÉ: Omo ìlú ibo ni? TÚNJÍ: Omo ìlú Améríkà … More Dialogue 1 – Unit 3 “Sísòrò nípa ènìyàn” (Talking about people)