Dialogue 1 – Unit 4 “Wíwá ilé láti réntì”(Looking for a place to rent)

Kimberly is looking for a one-bedroom apartment and goes to Mr. Makinde’s office for help. Mr. Makinde is a realtor. KIMBERLY: E káàsán sà ÒGBÉNI MÁKINDÉ: Òo. káàsán. Báwo ni nnkan? KIMBERLY: Dáadáa ni. E jòó, mo n wá ilé tí mo lè réntì. ÒGBÉNI MÁKINDÉ: Irú ilé wo ni o fé? KIMBERLY: Mo fé ilé tí … More Dialogue 1 – Unit 4 “Wíwá ilé láti réntì”(Looking for a place to rent)