Unit 5 – Dialogue 1 “Nnkan ojà àti aso” (Market products and clothing)

Kimberly now tells Tunji remaining things she needs for her house. KIMBERLY: Sé o máà lè lo sójà pèlú mi lóla? TUNJI: O ò tí ì so nnkan tí o so pé o fé lo rà l’ójà fún mi. KIMBERLY: Mo fé ra èro telifísònnù TUNJI: Kí l’o fé fi  èro telifísònnù se pèlú gbogbo isé re … More Unit 5 – Dialogue 1 “Nnkan ojà àti aso” (Market products and clothing)