Comprensión de lectura

Lee el siguiente diálogo y responde a las preguntas. DÉLÉ: Báwo ni nnkan? OLÚ: Dáadáa ni. Sé àlàáfíà ni? DÉLÉ: Àlàáfíà ni OLÚ: Níbo l’ò n lo? DÉLÉ: Mo n lo s’ojá OLÚ: Sé o lè ra búrédì fún mi? DÉLÉ: Rárá OLÚ: Kí l’ó dé? DÉLÉ: N ò lówó. Má bínú. OLÚ: Kò burú. Ó dàbò. DÉLÉ: Ó dàbò. PREGUNTAS ¿Por qué Dele … More Comprensión de lectura